Wo bí àwọn akẹ́kọ̀ọ́ kan ṣe pe Ògún, Ṣàǹgó, Ọ̀ṣun sọ̀kalẹ̀

Àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ile ẹkọṣẹ olukọni agba to wa ni Oṣiẹlẹ nilu Abẹokuta niya.

Awọn aṣa ati iṣe ilẹ̀ Yoruba ni wọn n gbe ga ninu fọnran yii.

Lara awọn ohun ti wọn n ṣe ni kiki awọn oriṣa ilẹ Yoruba.

Lara awọn oriṣa abalaye Yoruba ti wọn ki ni Ọṣun.

Ọṣun jẹ Oriṣa ti o ni ṣe pẹlu omi ni ilẹ Yoruba.

Pataki julọ lara awọn ilu ti wọn ti n bọ Ọṣun nilẹ Yoruba ni Igede Ekiti, Ile Ifẹ ati Osogbo nibi ti dun Ọṣun Oṣogbo ti maa n waye lọdọọdun.

Bakan naa ni wọn tu ki Sango.

|sango jẹoriṣa ti igbagbọ Yoruba gba pe o wa ni akoso sisan ara. Bakan naa ni itan sọ wi pe ba ni lode Ọyọ nigba iwaṣẹ.

Lara awọn ohun ti a mọ Sango si ni agbara nla to ni eyi to fi n yọ ina lẹnu.

Awọn akẹkọọnaa tun ki oriki Ogun, Mọremi,