Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́

Ìye àkókó tí a fi kà á: Ìṣẹ́jú 1

Aarẹ Bola Tinubu ti sọ fun ileeṣẹ ọlọpaa pe oun n reti lati gbọ pe ọwọ ti tẹ awọn to ṣekupa eeyan to le ni igba nipinlẹ Benue

Aarẹ lo sọ ọrọ naa lasiko abẹwo rẹ sipinlẹ ọhun lẹyin ifẹmiṣofo to waye nibẹ

Ọpọ eeyan ipinlẹ naa lo wọ aṣọ dudu lati pade Aarẹ lasiko ibẹwo rẹ ọhun

Ẹkurẹrẹ wa loju opo BBC Yoruba

__________________________________________

Onimọ nipa ọrọ to n lọ kan, Kayode Oladipupọ ti sọ pe

Ko buru bi awọn alaṣẹ fasiti OOU ṣe fọwọ gbe ọmu awọn akẹkọọ kan lati mọ boya wọn wọ kọmu wa sile ẹkọ

__________________________________________

Awọn adigunjale ti ṣakọlu sawọ ile itaja kan lagbegbe Mokola, nilu Ibadan

Awọn oṣoju mi koro sọ pe ko din ni eeyan mẹta to farapa ninu ikọlu ọhu

Fun ẹkunrẹrẹ