Wo ibi tí Oduduwa rọ̀ sí nílùú Ile Ife àti pàtàkì rẹ̀ fún ìdàgbàsókè ilẹ̀ Yorùbá
Wo ibi tí Oduduwa rọ̀ sí nílùú Ile Ife àti pàtàkì rẹ̀ fún ìdàgbàsókè ilẹ̀ Yorùbá
Itan fi idi rẹ mulẹ pe Oduduwa ni baba Yoruba at iwi pe ilu Ile Ifẹ lotẹwọnrọ si nigba to n ti ode ọrun bọ lorilẹ aye.
Ninu fidio yii, BBC News Yoruba ṣe iwadii lọ si ibi ti itan sọ pe Oduduwa rọ si nigba to gunlẹ si ilu Ile Ifẹ.
Ile Ifẹ ni wọn ni Olodumare ran Oduduwa si, ibi ti o si wọ si ni wọn n pe ni ojubọ Oduduwa nilu Ile Ifẹ.