Hero Tortoise: Ìjàpá 14 ni wọn yà sọ́tọ̀ láti bí Ìrère 2000, kí ìran wọn má baà parun
Iran awọn ijapa ti n lọ lorilẹ aye amọ ọna ti iran ijapa ko fi ni parun lo mu ki wọn ya ijapa mẹrinla sọtọ fun, ni Santa Cruz to wa lagbegbe Galapagos Isle, lorilẹede Espannola.
Ni aadọta ọdun sẹyin, ijapa meji pere lo wa lorilẹede naa, eyi to mu ki wọn gunle akanse eto ọsin ijapa, ki iran ijapa maa baa parun lorilẹ aye.
- Onínúfùfù ni Saheed Oṣupa, ṣùgbọ́n èèyàn dáradára ni-Taye Currency
- "Inú mi kìí dùn torí ẹ̀ẹ̀kan lọ́dún mẹ́rin ni ọjọ́ ìbí mi máa ń wáyé"
- Èmi àti Kolington kò fẹ́ra padà o, ọba Wákà kò fẹ́ ọba Fuji mọ́ - Salawa Abeni
- Kàyééfì ńla! Pẹ̀lúmi lu odindi ìlú kan ní jìbìtì ẹgbẹ̀lẹ́gbẹ̀ owó
- Ọ̀ọ̀ni kò láṣẹ láti yọ mí nípò, mi ò sì ní ááwọ̀ mọ́ pẹ́lú Aláàfin-Oluwo
- Nàíjíríà, ẹ fakọyọ lórí ìdènà Coronavirus àmọ ìròyìn òfegè léè ṣọṣẹ́ tẹ̀ bá ṣọ́ra - WHO
Awọn ijapa naa si lo bi ọmọ to ti le ni ẹgbẹrun meji bayii sugbọn ogbologbo ijapa kan wa ninu wọn, to ti le ni ọgọrun ọdun, to si bi ọmọ to le ni ẹgbẹrin.
Iroyin naa ni Diego lorukọ ijapa ọlọmọ pupọ naa, to si ti fẹyinti lẹyin isẹ asekara lati daabo bo iran rẹ ko maa baa parun.