George H. Bush, ààrẹ Amerika tẹ́lẹ̀ jáde láyé

Oríṣun àwòrán, Getty Images
George H. Bush, ààrẹ Amerika tẹ́lẹ̀ ti jáde láyé lẹni ọdun mẹrinlelaadọrin
Ọmọ rẹ, George W Bush, lo kede rẹ iku rẹ.
Aarẹ George HW Bush ni aarẹ kọkanlelogoji lorilẹede Amẹrika lẹyin ti o ti jẹ igbakeji fun aarẹ Ronald Reagan fun saa meji.
Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:
Laarin ọdun 1989 si 1993 ni o fi jẹ aarẹ, ṣugbọn ilepa rẹ fun saa keji foriṣanpọn nigba ti aarẹ Bill laa mọlẹ ninu idibo aarẹ to waye lọdun 1992.
Lara awọn to jagun ofurufu lasiko ogun agbaye keji ni ki o to wọ inu oṣelu lọ ni ọdun 1964 gẹgẹ bii ọmọ ẹgbẹ oṣelu Republican.
Lẹyin iku iyawo rẹ, Barbara ni oṣu kẹrin ọdun yii ni wọn gbe e lọ sile iwosan fun itsju aisan kokoro kan .
This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.
End of X post













