Osun election 2022: Ohun tóo ní láti mọ̀ nípa àwọn olùdíje Gomina Osun

Kaakiri Naijiria ati awọn orilẹede agbaye ni wọn ti n reti igberasọ ati aṣekagba idibo ti yoo waye lọla ọjọ Abamẹta ọjọ Kẹrindinlogun Oṣu Keje ọdun 2022 ni Osun.

Awọn ara ipinlẹ Osun yoo maa tuyaya tuyaya jade lọ si awọn ibudo idibo wọn lati lọ yan ẹni ti wọn fẹ gẹgẹ bii gomina ninu gbogbo awọn oludije to gbe apoti ibo.

Ẹwẹ, eyi ni awọn koko ọrọ to yẹ kẹẹ mọ nipa awọn àwọn tí nu n kun lori wọn ju laarin awn oludije to gbe igba idibo yii. Tẹ orukọ eeyan kọọkan lati ka nipa wọn.

Lapapọ, orukọ ati ẹgbẹ oṣelu gbogbo awọn oludije naa lọlọkan o jọkan niyii:

1. A - Akinade Akanmu Ogunbiyi

2. AAC - Awojide Peter Segun

3. ADP - Kehinde Munirudeen Olumuyiwa Atanda

4. APC - Adegboyega Isiaka Oyetola

5. APM - Awoyemi Oluwatayo Lukuman

6. APP - Adebayo Adolu Elisha

7. BP - Adeleke Adesoji Aderemi

8. LP - Yussuff Sulaimon Lasun

9. NNPP - Razaq Oyelami Saliu

10. NRM - Abede Adetona Samuel

11. PDP - Adeleke Ademola Jackson Nurudeen

12. PRP - Ayowole Olubusuyi Adedeji

13. SDP - Omigbodun Oyegoke Akinrinola

14. YPP - Ademola Bayonle Adeseye

15. ZLP - Adesuyi John Olufemi

Àwọn ìròyìn tí ẹ lè nìfẹ sí