Ahmed Gulak's death: Àwọn jàndùkú agbébọn ṣekúpa Ahmed Gulak, olùdàmọ́ràn Goodluck Jonathan

Awọn janduku agbebọn ti ṣekupa Ahmed Gulak tii ṣe oluranlọwọ aarẹ ana orilẹ-ede Naijiria, Goodluck Jonathan.

Ilu Owerri nipinlẹ Imo ni wọn ti sọ pe wọn yinbọn pa Gulak.

Gulak n rinrin ajo lati Abuja si Owerri lalẹ ọjọ Abamẹta ki o to ṣagbako iku ojiji lọna.

A o maa mu ẹkunrẹrẹ iroyin naa wa fun laipẹ.