Akomolede ati Aṣa lori BBC Yoruba: Ẹ̀yà Ara Ifọ̀ ní olùkọ́ Adedokun kọ́ wa

Kini a n pe ni ẹya ara ifọ?

Eto Akomolede ati Asa lori BBC Yoruba toni ti jade nibi ti a ti n gbe ẹya ara ti a n lo fun iro ede pipe wo.

Arabinrin Adedokun Ronke ni olukọ wa lati ile ẹkọ Emmanuel Agboola Baptist Grammar School, Kajola ni Ogbomoso ni ipinlẹ Oyo.

Kini a n pe ni iro aikunyun ati iro akunyun?

Kini pataki eyin oke, ahọn ati komookun nigba ti eeyan ba n sọrọ?

Kọ sii nipa ẹya ara ti a n lo fun iro ede pipe nigba ti a ba nṣafọ.

Awọn ẹya ara wo ni a le fi oju ri?

Awọn wo ni a ko le fojuri to si ṣe pataki fun iro ede pipe?

Olukọ Adedokun Ronke tun ṣalaye kikun lori awọn afipe asunsi ati akanmọlé

Mọ sii nipa iro akunyun ati iro aikunyun.