Akomolede àti Asa: Ìyàtọ̀ tó wà láàrin ìlànà ìpolówó ọjà láyé àtijọ́ àti òde òní

Ipolowo ọja ni agunmu owo, gẹgẹ bi Yoruba se maa n sọ.

Bẹẹ si ni ọja tabi isẹ ti eeyan ko ba polowo rẹ yoo di okuta ni, idi si ree ti ilana ipolowo ọja nilana adayeba kii fi se ohun amusere.

Lori eto Akomolede ati Asa lọsẹ yii, olukọ wa, Olayinka aya Olorunyolemi tile ẹkọ girama St Louis nilu Akure kọ wa nipa ipolowo ọja nilẹ Yoruba.

Bakan naa lo mẹnuba awọn ọna ara ta maa n gba polowo ọja ati isẹ laye atijọ, bẹẹ lo tun mẹnuba oniruuru awọn ọja to wa bii ọja owurọ, ọsan ati alẹ.

Àwọn ìtàn mánigbàgbé tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:

Ẹ wa nnkan fidi le lati wa kẹkọ ilana ipolowo ọja nilana abalaye lori eto yii, ẹ ku ikalẹ.