You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Akomolede àti Asa: Kí ni Ìjálá láàrin àwọn ewì alohùn àti bí wọ́n ṣe ń sun-ún?
Ki ni Yoruba n pe ni Ijala, irufẹ awọn eeyan wo lo n sun, asiko wo ni wọn n sun ati pe bawo ni wọn se n sun Ijala?
Lọsẹ yii lori eto Akomolede ati Asa lori BBC Yoruba, Arabinrin Modupe aya Azzez, tii se olukọ ile ẹkọ girama Akure kọ wa nipa Ijala sisun.
Ninu alaye rẹ, aya Azeez ni Ijala jẹ ere awọn ọdẹ , to si sọ nipa iyatọ to wa laarin Ijala ati Iremoje, eyi tawọn ọdẹ maa n sun lasiko ti ọkan ninu wọn ba ku.
- Èmi kìí ṣe ọmọ eléégún ṣùgbọ́n mò ń pe kísà sí ẹ̀ṣà- Òkòtò akéwì
- Sọ̀rọ̀sọ̀rọ̀ tí wọ́n fẹ̀sùn kàn pé ó bú Lai Mohammed gbá ìtúsílẹ̀ lẹ̀yìn ọjọ́ 45 látìmọ́lé
- Ẹ̀yà Adúláwò kún fún oríṣiríṣi àrà- Karin Berber
- Mo fẹ́ máa kọ "Classical" lédé Ijebu, Hausa, Igbo Pidgin - Abiodun Koya
- Lekan kingkong lọmọ Yorùbá tó ń fi òwe dárà lẹ́yìn odi
- Ṣé ẹ̀yin ti rí ọkùnrin tó ń sún ẹ̀kún ìyàwó rí?
Bakan naa la tun kọ nipa ọna tawọn ọdẹ maa n gba lo Ijala lati fi ki ara wọn, se abẹwo sira wọn ati awọn itan nipa Ijala to ti waye ri.
Bakan naa ni olukọ ede Yoruba naa tun kọ wa nipa awọn aseyọri awọn ọdẹ to ti waye sẹyin lati ipasẹ Ijala ati oriki awọn ẹranko nla nla tawọn ọdẹ ti pa ninu igbo.
- Ìjà Awolowo, Akintola àti ogun 'Wẹtiẹ', ẹ̀kọ́ wo ló kọ́ wa?
- Igbo Olodumare rèé, níbi tí Ìgbín ti tóbi ju Ìjàpá lọ
- Ìdílé márùn-ún tó gbajúmọ̀ fún òwò ẹrú nílẹ̀ Yorùbá
- Wo ìtàn ayé gbajúmọ̀ adigunjalè méje nílẹ̀ Yorùbá
- Jimoh Odutola, akọni oníṣòwò tí kò kàwé, àmọ́ táwọn Ààrẹ orílẹ̀-èdè ń ké sí láti wá dá iléesẹ́
Ẹ fara balẹ lati kọ ẹkọ toni lori eto yii nipa Ijala sisun.