How well do you speak Yoruba: Kíni Yorùbá ń pé ní 'Pen'?

BBC Yoruba wa fun gbigbe ede ati asa Yoruba ga.

Ohun ti a da a sile fun ni lati mu idagbasoke ba ede ati aṣa Yoruba ni agbaye.

Se ẹyin dantọ ninu ede Yoruba sisọ?

To ba jẹ bẹẹ, kini Yoruba n pe 'Pen'?

A wadii boya awọn eniyan mọ nkan ti wọn n pe "pen" ni ede Yoruba.

Esi ti a ri gba ya wa lẹnu.

Bi awọn kan ṣe ni kalamu ni, ni awọn miran ni bíìrò ni, lawọn miran ni gege ikọwe ni ti awọn miran ni takada ni

Awọn iroyin ti ẹ lee nifẹẹ si: