You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Coronavirus: Ǹjẹ́ àwọn dókítà tó ń tọ́jú eyín ń ṣisẹ́ lásìkò pàjáwìrì? Àti àwọn ìbéèrè míràn
O ti lé ni mílíọ̀nù mẹ́ta àti ọgọ́rùn ún mẹ́fà (3,600,000) ènìyàn to ni Corornavirus ni gbogbo àgbáyé tí ẹgbẹ̀rún lọ́nà ọtalenigba (251,000) ènìyàn ti kú- ẹgbẹ̀rún lọ́nà mokandinlogbonẹgbẹ̀run (29,000) nínú rẹ̀ ló wá láti UK nìkan.