You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Kini itumọ ‘International passport’ l'ede Yoruba?
BBC Yoruba ko fẹ ki ede Yoruba parun ni iran yii ni a ṣe maa n ran ara wa leti awọn ọrọ kan ki a le tumọ rẹ fun ara wa.
Loni, itumọ International Passport ni a fẹ kọ ara wa ni ede Yoruba.
- Ọlọ́pàá mú pásítọ̀ tó kó àwọn ọmọ ìjọ pamọ́ sí àjà ilẹ̀ l'Ondo, Ó ní oṣù kẹsàn án ni 'Jesu' yóò dé
- A ti gbáradì fún ikọ̀ Super Falcons – Banyana Banyana ti South Africa
- Osun 2022- Iléeṣẹ́ ọlọ́pàá nawọ́ gán afurasí ọ̀daràn 18
- MaryGotFit -obìnrin bí ọkùnrin agbírinsápá ṣàlàyé ìdẹ́yẹsí tó ń kojú nídìí iṣẹ́ tó yàn láàyò
Itumọ "international passport" l'ede Yoruba ni iwe irinna Agbaye.