Nigerian Fraudsters: Ìwádìí BBC fihàn pé ìdajì àwọn gbájúẹ̀ lágbàyéé wá láti Nàíjíríà
Ileesẹ BBC se aknase iwadii kan nipa awọn ọdọ to n lu jibiti lati ori ayelujara taa mọ si Yahoo Boys ati ohun to sun wọn de ibẹ.
Iwadii naa si fi han pe ọpọ awọn gbajuẹ yii lo maa n lo oju opo BEC lori ayelujara lati dibọn bii ọga ileesẹ kan, ti wọn yoo si gba owo lọwọ ẹni to ba ba wọn dowo pọ.
Iwadii ọhun tun fi han pe orilẹede aadọta lagbaye ni awọn onijibiti naa wa amọ idaji wọn lo jẹ ọmọ Naijiria.
Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:
- Ìtàn ayé Taiwo Oredein rèé, àgbà òṣèlú tó parí ayé rẹ̀ sọ́gbà ẹ̀wọ̀n
- Ìtàn ìgbé ayé Bode Thomas rèé, ó kọ́ wa láti máa kó ẹnu wa ní ìjánu
- Ṣo mọ̀ pé J.F Odunjo jẹ aṣòfin àti mínísítà nílẹ̀ yìí, yàtọ̀ sí pé ó jẹ́ òǹkọ̀wé?
- Ó pé ọdún mẹ́rìnlélàádọ̀ta tí Akintola kú, ìdí abájọ ìja rẹ̀ pẹ̀lú Awolowo rè é
- Ìtàn Gbọnka àti Timi, akọni méjì tó borí Aláàfin Ṣango
- Wo ìṣẹ̀lẹ̀ márùn-ún tí kò bá pín Nàíjíríà sí yẹ́lẹ-yẹ̀lẹ
Bẹẹ ba si gbagbe, laipẹ yii si ni ọwọ tẹ gbajumọ onijibiti kan lati Naijiria, Ramon Abass, ti ọpọ eeyan mọ si Hushpuppi ati awọn mẹta miran.
Ọkan ninu awọn ọdọ gbajuẹ to ba BBC sọrọ ni oun fẹ lowo bi oludari oju opo Facebook, Mark Zuckerberg ni oun se n lu jibiti.
Fidio yii si lo tu asiri ọna tawọn ọdọ ọmọ Naijiria naa n gba lu jibiti naa atawọn ọsẹ ti wọn ti se.



