Yemen Water Child: Ọmọdé 44 ni Sọ́jà pa, tí 100 míì sì kú látọwọ́ ohun ìjà olóró
Ase ibi gbogbo ni wọn ti n ko adiẹ alẹ, akoko kan yatọ sira wọn ni.
Bẹẹ ni ọrọ ri pẹlu awọn agbofinro to n sekupa awọn ọmọde ti ko gbe ohun ija lọwọ, tabi mọwọ mẹsẹ ninu iwa ọdara,
Akọtun isẹlẹ mii to tun waye nidi eyi ni ti ọmọde kan, Ruwaida, ti sọja fi ibọn fọ ori rẹ lorilẹede Yemen.
Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:
- Wo ẹ̀bùn àti owó tí àwọn olùkópa ti jẹ lórí ètò BBNaija season 5
- Kíni 'Ẹ̀lẹ̀ daddy' Olorì Abbey Adeyemi ṣe tí ojú òpó ayélujára Instagram rẹ̀ fi ń yeruku lálá?
- Ìkébé mi tóbí ju ohun tí mo lè dọwọ́ bò lọ, n kìí fí ṣakọ- Nkechi Blessing
- Ẹ̀yin òṣìṣẹ́, ẹ má ṣáì lọ síbi iṣẹ́ lọ́jọ́ Ajé, olórí àwọn òṣìṣẹ́ ní Nàìjíríà tako ìyanṣẹ́lódì
- Ọgbọ́n àti kówójẹ n'ìgbèsẹ̀ ìjọba láti ná $1.95bn sórí reluwé làti Kano sí Niger Republic- PDP
Ẹsẹ kan aye, ẹsẹ kan ọrun si ni ọmọ ọdun mẹfa naa wa bayii nile iwosan, ti awọn ẹbi rẹ si ti n sọ ohun toju wọn ri lori ayelujara.
Nigba to n ba BBC sọrọ, akọroyin kan ni iwadi fihan pe o ti to ọmọde mẹrinlelogoji ti awọn sọja ti fi ibọn pa nigba ti ọgọrun miran ku lati ọwọ ohun ija oloro.