You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
NULGE election: Ẹgbẹ́ NULGE Oyo dìbò yan olóyè ẹgbẹ́ tuntun èyí tó tako àṣẹ iléẹjọ́
Ẹgbẹ awọn oṣiṣẹ ijọba ibilẹ NULGE, ẹka ti ipinlẹ Oyo, ti dibo yan awọn oloye igbimọ alaṣẹ tuntun fun ẹgbẹ naa.
Eto idibo ọhun to waye lalẹ tako aṣẹ ileẹjọ to sọ pe ki wọn si da etro idibo naa duro naa.
Adajọ N. C. S. Ogbuanya ti ileẹjọ to n ri si ọrọ awọn oṣiṣẹ ọba niluu Eko lo fote le eto idibo awọn oloye ẹgbẹ tuntun.
- Ka ìròyìn yìí láti fi orúkọ sílẹ̀ fún owó ìrànwọ́ ìjọba àpapọ̀ Nàìjíríà!
- Lawuyi Ogunniran, àgbà ọ̀jẹ̀ òǹkọ̀wé Eégún Aláré dágbére fáyé!
- Hisbah mú ọkùnrin mẹ́ta tó pín fídíò ìfipábánilòpọ̀ ọmọdébìnrin 16 tó fẹ́ ṣèyàwó lórí ayélujára
- Asiwaju BolaTinubu sọ̀rọ̀ lóríi ìròyìn ẹlẹ́jẹ̀ pé òun gbà pé APC fìdí rẹmi ní Edo
- Wo bí Sunday Shodipe ṣe pa Funmilayo tó pa kẹ́yìn l' Akinyele
- Ọlọ́jọ́ Festival 2020:Ọ̀ọ̀ni ti Ilé Ifẹ̀ tí wọ ìléèdí ọlọjọ méje tí kò ní rí ẹnikẹ́ni sójú
Ẹjọ to wa nile ẹjọ ọhun da le ẹjọ ti Ọgbẹni Hakeem Ojo Oyewo pe wi pe wọn yọ oun kuro gẹgẹ bi ọkan lara awọn oludije fun ipo aarẹ ẹgbẹ NULGE.
Ofin yii si wa sibẹ, bẹẹ ni ko si le jẹ ki wọn ṣe eto idibo miiran titi ẹjọ naa yoo fi ni iyanju nile ẹjọ.
Amọ, ni idaji ni wọn dibo yan Kọmureedi Ayobami Olusegun Adeogun gẹgẹ bi alaga ẹgbẹ NULGE ipinlẹ Oyo.
Nigba ti wọn kde rẹ tan gẹgẹ bi ẹni to jawe olubori ninu eto idibo naa, Kọmureedi Adeogun ṣeleri pe oun ko ni ja awọn ọmọ NULGE kulẹ.
- Tí ìjọba bá gbé òfin kónílé-ó-gbélé ọlọ́jọ́ pípẹ́ míì kalẹ̀ nítori Covid-19, ǹkan yóò bàjẹ́ ní Naijiria- Dokita
- OPC láwọn mú afurasí agbébọn ajínigbé mẹ́rin l'Oyo, ọlapàá ní àpapọ̀ òṣìṣẹ́ elétò aàbò ló ṣiṣẹ́ náa
- INEC fún Obaseki ní ìwé-ẹ̀rí moyege gẹ́gẹ́ bí gómìnà tí wọ́n ṣẹ̀ṣẹ̀ dìbò yàn
- WASSCE: Ìpínlẹ̀ Delta fòfin de olùkọ́ 41 tó ṣe màgòmágó nínú ìdánwò
Alaga tuntun naa sọ pe oun ko ni ṣai maa tọ ipasẹ awọn to ti dipo olori mu ninu ajọ naa tẹlẹ.
O gbadura wi pe ki Eleduwa jẹ ki oun ruure ki oun sọ ọ 're.
- Wo àwọn ìlúmọ̀ọ́ká tó ṣe ìgbéyàwó ní ọdún 2020 yìí
- Bah N'Daw àti Assimi Goita di adarí tuntun láti tukọ̀ orílẹ̀-èdè Mali ní ọdún kan àti aàbọ̀
- Orílẹ̀èdè Amẹrika ti bẹ̀rẹ̀ sí ní wo wọlé-wọ̀de Atiku, àwọn ìyàwo rẹ̀ lórí owó tí wọ́n kó lọ sí òkèèrè
- Ọ̀gá iléeṣẹ́ gbé £10 mílíọ̀nù ẹ̀bùn owó fún òṣìṣẹ́, èyí lohun tó pawọ́n pọ̀
- Ìjọba Katsina ní kí àwọn iléèwé wà ṣì ní títìpa nítorí arùn Coronavirus