Coronavirus updates: 'Kòkòrò covid-19 kékeré ti mọ́ṣálááṣí pa, há àwọn èèyàn mọ́lé'

Àkọlé fídíò, 'Coronavirus kò jẹ́ kí n lè lọ kírun mọ́ ní mọ́ṣálááṣí'

Aarun coronavirus ti ṣakoba fun wa lọpọlọpọ, bayii lawọn ọmọ orilẹde Kenya to ba BBC Yoruba sọrọ ṣe sọ.

Awọn to jẹ ẹlẹsin musulumi ninu wọn sọ pe coronavirus ko jẹ kawọn lanfaani mọ lati lọ kirun ni mọṣalaaṣi.

Bakan naa lawọn mii n ṣaroye pe iṣede covid-19 ti ṣe ipalara fun okowo awọn.