Coffee Painter: Adebukola ní kò sí ìrànwọ́ lẹ́yìn ẹ̀kọ́ girama lòun ṣe ń ya àwòrán
Yoruba ni ori lo mọ isẹ asela, ki sba oke ma jẹ ka daamu, ka to ja ọna.
Ọdọmọbinrin kan ree, Adedamọla Adebukọla, ti ko ni oluranlọwọ lẹyin eto ẹkọ girama, amọ ti ko setan lati gbe igba nabi abi tọrọ agbe, sugbọn to wa ohun ti yoo se jẹun dọjọ alẹ
Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:
- 'Ọjọ́ lọjọ́ tí mo mọ̀ pé wọ́n bí mi láà ní ojú ara obìnrin àti ilé ọmọ'
- Àwọn akẹ́kọ̀ọ́ Nàìjíríà ní Ukraine wà nínú ìbẹ̀rù-bojo lẹ́yìn tí Russia yin àdó olóró sí Ukraine
- Èèyàn méje kú, ọ̀pọ̀ farapa bí Russia ṣe bẹ̀rẹ̀ ìkọlù sí Ukraine
- South Sudan ṣì ń ṣẹ̀jẹ̀, àwọn orílẹ̀èdè alámùúlétì rẹ̀ figbe ta
- Ilé ẹjọ́ ju Evans ajínigbé sẹ́wọ̀n gbére
Kini Adebukola tun sọ nipa sise amulo kọfi fun isẹ́ ọnà?
Nigba to n ba BBC Yoruba sọrọ, Adebukọla ni osu marun pere ni oun fi kọ isẹ aworan yiya, eroja ohun mimu kọfi, Zobo ati tii elewe Lipton si ni oun fi maa n ya aworan.
O ni owo ti wọn fi n ra ọda lati fi ya aworan ti kọja agbara oun, ni oun se yan lati maa lo awọn eroja naa, ti owo wọn ko gunpa rara.
Ayaworan kọfii naa ni isẹ kekere owo nla ni fifi kọfi ya aworan jẹ nitori owo nla lo n mu wa fun oun.










