You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Coronavirus: Ọ̀pọ̀ àwọn arìnrìnàjò wá sí Nàíjíríà ló kọjá àbẹ̀wò tó lágbára
Nibayii ti arun Coronavirus ti wọ orilẹede Naijiria, ijọba wa ko sun rara, lati dena itankalẹ arun naa.
Amọ ijọba wa ti n gbe igbesẹ lati dena itankalẹ arun naa bayi bẹrẹ lati awọn papakọ ofurufu ilẹ wa.
- Àlárùn Coronavirus di 7000 lágbàyéé, ìjọba Nàíjíríà kọjú oro sí ọjà China tó jẹ́ ẹbu
- Kí ni ìjọba ń ṣe lórí ààrùn Coronavirus tó wọ Nàìjíríà?
- 'Mi ò fẹ́ gbé àrùn Coronavirus lọ sí Áfíríkà'
- Ọmọ Nàìjíríà di agbábọ́ọ̀lù àkọ́kọ́ tó ní ààrùn Coronavirus
- Ààrùn coronavirus ti ràn dé ilẹ̀ Afirika, Egypt ló kọ́kọ́ yà
- A kò fẹ́ kẹ kó àwọn ọmọ wa tó wà ní China wálé, kò sí ìtọ́jú fún àrun Coronavirus níbí - Ilé aṣojú-ṣòfin
- Kò sí Coronavirus l'Eko, èsì àyẹ̀wò ọmọ China fìdí ẹ̀ múlẹ̀!
BBC Yoruba ṣe abẹwo si papakọ ofurufu wa, ta si ri itu meje ti awọn osisẹ ibẹ n pa lati ri pe wọn se ayẹwo fun awọn eeyan naa.
Ẹ wo fidio yii lati mọ bo se n lọ nibẹ.