Coronavirus: Ọ̀pọ̀ àwọn arìnrìnàjò wá sí Nàíjíríà ló kọjá àbẹ̀wò tó lágbára

Àkọlé fídíò, Coronavirus: Ọ̀pọ̀ àwọn arìnrìnàjò wá sí Nàíjíríà ló kọjá àbẹ̀wò tó lágbára

Nibayii ti arun Coronavirus ti wọ orilẹede Naijiria, ijọba wa ko sun rara, lati dena itankalẹ arun naa.

Amọ ijọba wa ti n gbe igbesẹ lati dena itankalẹ arun naa bayi bẹrẹ lati awọn papakọ ofurufu ilẹ wa.

BBC Yoruba ṣe abẹwo si papakọ ofurufu wa, ta si ri itu meje ti awọn osisẹ ibẹ n pa lati ri pe wọn se ayẹwo fun awọn eeyan naa.

Ẹ wo fidio yii lati mọ bo se n lọ nibẹ.