Dementia: Máṣe pe arúgbó rẹ ní àjẹ́ tàbí wèrè torí pé làákàyè rẹ̀ ń ṣíṣẹ kíṣẹ́ lọ́jọ́ ogbó

Àkọlé fídíò, Dementia: Máṣe pe arúgbó rẹ ní àjẹ́ tàbí wèrè torí pé làákàyè rẹ̀ ń ṣíṣẹ kíṣẹ́ lọ́jọ́ ogbó

Lorilẹ Afirika, ọpọ idẹyẹsi lawọn ọdọ maa n se sawọn arugbo wọn to ba ni arun to nii se pẹlu ọjọ ogbo eyi to n mu ki ọpọlọ wọn se isẹkisẹ, taa mọ si Dementia.

Ọpọ wọn lo n pe awọn arugbo to n tọ sara, gbagbe nkan, tabi ki ọrọ wọn ma ba taye mu, ni were ati ajẹ, eyi ti ko dara.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:

Ninu fidio to n lanilọyẹ yii, awọn olutọju arugbo kọ wa ni awọn ohun to yẹ ka se lati setọju awọn arugbo yii, ki ọjọ alẹ wọn lee rọrun fun wa.