Africa Eye: Ìjìjàgbara fún àwọn ọmọdébìnrin tó wà lọ́wọ́ ewu

Africa Eye

Ikọ ọtẹlẹmuyẹ Africa Eye tun de orilẹede Congo nibi to ti finmu finlẹ nipa igbe aye awọn ọdọbinrin ti wọn dagba soju popo.

Fidio naa ree:

Àkọlé fídíò, Africa Eye: Ìrírí àwọn ọ̀dọ́bìnrin tó dágbà sójú pópó àti ìrètí wọn fún ọjọ́ ọ̀la