Ọ̀sẹ̀ ilẹ̀ Afíríkà rèé nínú àwòràn: 31 May - 6 June 2019

Arìnrìn oge Alek Wek dé gbọ̀ngan 2019 CFDA fún àyẹyẹ ami ẹ̀yẹ ni New York

Oríṣun àwòrán, AFP

Àkọlé àwòrán, Arìnrìn oge Ọmọ bíbí South Sudan Alek Wek takes tyan fanda ni ibi ayẹyẹ CFDA fún àmì ẹ̀yẹ fún ohun àmusoge tó wáye ní New York lọ́jọ́ ajé
Presentational white space
Mamello Makhabane ọmọ South Africa ń yàwọràn sáájú ife ẹ̀yẹ àgbáyé

Oríṣun àwòrán, FIFA/Getty Images

Àkọlé àwòrán, Ní ọjọ́rú, àgbábọ̀ọ̀lù ọmọ ilẹ̀ South Africa fẹ́yin kẹẹ si ẹ̀rọ ayàwòràn sáájú ife ẹ̀yẹ àgbáye àwọn obìnrin tó ń lọ niFrance.
Presentational white space
Awọn ẹlẹsin Musulumi to lọ Yidi ni Ibadan, Ipinlẹ Ọyó
Àkọlé àwòrán, Ní Ìpínlẹ̀ Ọyọ lórilẹ̀ èdè Naijíríà àwọn mùsùlúmi ó gbẹ́yìn láti lọ sàdúra ní yidi fún ìtúnu àwẹ
A ri ọmọ kékeré yìí láàrín àwọn musulumi níbí àdúrà yídì, èyí ti wọn fí ń ṣe ìtúnu ààwẹ Ramadan ní yidi Califonia ní Nairobi.

Oríṣun àwòrán, Reuters

Àkọlé àwòrán, Ní ọjọru kan náà ní àwọn mùsúlùmí ṣe ọdún Ramanda, bẹẹni ọmọdebínrin yìí kọ́ọ̀wọ́rin lọ fún àdúra yídì ní olú ilú Kenya tí a mọ si Nairobi.
Presentational white space
Awọn musulumi Kenya lọ si ibi àdúrà ọdun Eid-il-Fitri ni orile -èdè Kenya.

Oríṣun àwòrán, AFP

Àkọlé àwòrán, Ni Nairobi bakan náà a rí ọmọdékúnrin yiìí ni bi tí ó fi gbogbo ọkan gbàdúrà ní pápá yídi
Presentational white space
Presentational white space
Olonje kan ni Egypt tó maa n dána sààri ló sọ oruko sọọbu ounjẹ rẹ ni "Liver fuul''

Oríṣun àwòrán, AFP

Àkọlé àwòrán, "O ní dá ounjẹ jẹ" èyí jẹ ohun ti wọn kọ si àra apoti ounjé ní ]ilú Cairo ní ọjọ jimọ sáájú aṣekaágbá Liigi Uefa. Mo Salah tó jẹ ìlú mọ̀ọ́ka agbábọọlu ni Liverpool, èyi ti wọn ti yí pada si "Liver fuul"Egyptian footballer Mo Salah is the star player of winning side Liverpool, which has been changed here to "Liver Fuul" nínu ere kan ni Sudan ti wọn pe ni ounje ẹwa "Fuul".
Presentational white space
ololufẹ ere idaraya ọmọ Bangladesh duro ya foto ní ICC ife ẹyẹ agabye Krikẹti ti ọdun 2019 láàrin South Africa àti Bangladesh ní ọjọ keji oṣu kẹfa ọdun yii ni London.

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán, Lẹ́yìn ti South Africa fìdí rẹmi nínú ìfigagbága wọn pẹ̀lú Bangladesh lọjọ àìkú, èyí ti àwọn onímọ pè ni ìdíje to mú ìrunu báni jùlọ nínú eré ìdáya ife ẹyẹ agbaye Krikẹti ìmúra ọkan lára àwọn olólùfẹ ereidaraya ni Bangladesh.
Presentational white space
Pallbearers gbé posi Etienne Tshisekedi, tó jẹ olóri ọmọ ẹgbk alátako to ku ni Belgium ni ọdun meji seyin.

Oríṣun àwòrán, Reuters

Àkọlé àwòrán, Lẹ́yìn ọdún meji ti ó ti ku, wọn ṣẹṣẹ gbe posi ọga ẹgbẹ alátako Etienne Tshisekedi Káàkiri ní orilẹ̀-èdè DR Congo laja Jimọ... ní ìjọ Martyhrs of Pencost ní pápá ìṣere Kinshasa ní ọjọkọkanlelọgbọ̀n osu kaarun
Ololufẹ olori alatako to jẹ olori ijoba nigba kan ri ni won kerora lasiko ti won n gbe oku rẹ kọja.

Oríṣun àwòrán, AFP

Àkọlé àwòrán, Ọ̀pọ̀ ẹgbẹ̀run olólùfẹ́ rẹ ní wọn fọ́n sita láti fin ẹdun ọkan wọn han bi wọn se ń gbe oku rẹ̀ kọja ni opopona oluilu Dr Congo Kinshaha ní ọjọ kini oṣù kẹfa.
Presentational white space
Yiyọ òòrun ni Cairo ti se olu ilu Egypt ni ọjọ kin osu kẹfa.

Oríṣun àwòrán, Reuters

Àkọlé àwòrán, Orílẹ̀-èdè Egypt ni ilu Cairo ni a rti ri oorun to yọ yìí lọjọ satude.
Presentational white space

Aworan wa lati ọwọ Reuters, AFP, Getty Images ati EPA.