Plastic for School fees: Àwọn èèyàn rò pé wọ́n fẹ́ máa lò wá ni
Àwọn ike rọba yii n ran wa lọwọ lati ṣe ọpọlọpọ nkan to wulo bii irọrí, aṣọ itẹ ibusun.
Eyi ni ọrọ aṣoju ileeṣẹ to n ṣe ajọṣepọ pẹlu ile iwe kan ni agbegbe Ajegunle to gba obi laye lati maa fi ike san owo ile iwe àwọn ọmọ.
Wọn ṣalaye pe o ṣe anfani fun adugbo, fun ile iwe koda, ati fun awọn ile iṣẹ to n ṣe atunlo rẹ.