Yoruba gbayì! Óyá fi ààmì sórí 'Bobajiroro'

Àkọlé fídíò, Ǹjẹ́ o mọ Yoruba daju? Fi ààmì sórí 'Bobajiroro

Ede Yoruba jẹ ọkan gboogi ni agbaye ti aami ori rẹ jẹ kọkọrọ ti ẹnikẹni le fi tumọ rẹ.

Sunmọbi ki o ba wa fi aami sori ọrọ yii to ba jẹ ojulowo ọmọ Yoruba.

Àwọn ìròyìn mìíràn tí ẹ lè nífẹ̀ẹ́ sí: