Oshisko twins: Ojú wa rí, ṣùgbọ́n ìgbọ́raẹniyé ló ń ràn wá lọ́wọ́
Ibeji tootọ kọ ni Adigun Ọmọbọlanle Valentina pẹlu Oyedele Adebisi Yewande ṣugbọn wọn ti sọ ara wọn di ejirẹ ẹdunjọbi oyila lẹnu iṣẹ adẹrinpoṣonu lori ikanni agbaye Twitter, Instagram ati Facebook ni wọn.
Amọṣa, ki lo sun wọn yan orukọ, 'Oshisko twins' ati pe ki ni awọn ipenija ti wọn n dojukọ gẹgẹ bii ọrẹ meji to sọ ara wọn di ibeji ti wọn si tun yan iṣẹ amuludun laayo?
Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:
- Ilé ẹjọ́ kéde Ademọla Adeleke gẹ́gẹ́ bíi gómìnà ìpínlẹ̀ Ọṣun
- Ìyá àgbà Ọlayinka, arúgbó tó ń ṣoge bí omidan
- Baṣọ̀run Gáà, tó yan ọba mẹ́rin, pa ọba mẹ́rin àmọ́ ọba karùn-ún ló pa á
- Àràmọ̀ǹdà! Ọmọ ọdún mẹ́wàá ń fọn fèrè lágbo àríyá
- Ìtàn ọmọ Afirika tó ló lówó jùlọ lágbàyéé rèé
- Ohun tí Adeleke sọ rèé nígbà tí ìgbẹ́jọ́ èsì ìdìbò gómínà Oṣun bẹ̀rẹ̀
- Èmi ṣì ni Gómìnà ìpínlẹ̀ Ọṣun-Oyetọla