Sẹ́gílọlá: Arúgbó awẹ́lẹ́wà tó ń ṣiṣẹ́ omidan
Awọn agba bọ wọn ni arugbo ṣoge ri akisa lo igba ri. Eyi gan lo difa fun Sẹgilọla, iya agba to n ṣiṣẹ afaworan ṣoge, (modelling) ti ọpọ mọ mọ awọn omidan.
Gẹgẹbi ohun to sọ fun BBC News Yoruba, ko si ara ti omidan iwoyi n da ni oge ati ẹṣọ ti awọn arugbo ko tii fi lo gba nigba tiwọn.
Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:
- Baṣọ̀run Gáà, tó yan ọba mẹ́rin, pa ọba mẹ́rin àmọ́ ọba karùn-ún ló pa á
- Wo àwọn òrílẹ̀èdè 10 tó láyọ̀ jùlọ lágbàyéé
- Ajàfẹ́tọ̀ọ́ ẹni fẹ́ gbèjà ọmọ Naijiria tí ilé oúnjẹ China kò gba láàyè
- Àìsàn tó ń ṣe ọ ní ohun ṣe pẹlú oorun rẹ - Onímọ
- Yorùbá, ọmọ ọdún mẹ́jọ tà ọmọ òyìnbò yọ nínú ayò Chess l‘Amẹrika
- Òkùnkùn biribiri ni ìjìyà ẹ̀ṣẹ̀ ìjọba ìbílẹ̀ mẹ́fà nílẹ̀ Ìjẹ̀ṣà tó na òṣìṣẹ́ àjọ amúnáwá
- Kí ló dé tí obinrin tó ní HIV/AIDS fi pọ̀ ju ọkunrin lọ ní Nàìjíríà?
- Offa Bank Robbery: Àwọn ọlọ́pàá fí ìyà jẹ wá láti sọ nkan ti wọn fẹ ká sọ ni
- Kò sí èèyàn kánkan tó kù nílé tó wó ní Ibadan- NEMA