Building Collapse: Wọ́n yọ èèyàn mẹ́rin níbi ilé mííràn tó wó l'Eko

Ile mii to wo lu lẹ
Àkọlé àwòrán, Ile to tun wo l'Eko

Ile yii ti wá ní abé àwọn ile ti wọn ti pinu láti wo teletele kò tó di pé ó dawo ni ìrólé yii. Kò sí ẹ̀mí tó sínú níbi ilé náà. Àwọn tí oro naa soju wọn sọ pé àwon mẹ́rin ni ile naa wolu lásìkò tí wọn ń gbìyànjú láti ṣe àwo pale rẹ.

Ile mii to wo lu lẹ
Àkọlé àwòrán, Ile miran tun wo l'Eko

Wọn ní ní kété tí ẹni tó ní ilé náà ṣe gbó pé ìjọba tí yaa soto láti wòó ni ó fi kú àwọn tí yóò bá ṣe iṣẹ́ ilé Wiwo náà.

Ile mii to wo lu lẹ
Àkọlé àwòrán, Ile miran tun wo l'Eko
Ile mii to wo lu lẹ
Àkọlé àwòrán, Ile miran ta lu lẹ
Ile mii to wo lu lẹ
Àkọlé àwòrán, Ki ile naa to ya lu lẹ
Ile mii to wo lu lẹ
Àkọlé àwòrán, Ile miran wo L'Eko

Àwọn tọrọ soju wọn ṣàlàyé pé, wọn tí yọ àwọn méjì tó farapa nínú àwọn merin tó wà níbè wọn sì ti kó wọn lọ sí ilé ìwòsàn