HIV AIDS: Ìdí tí o kò fi lè kó àa[rùn HIV nínú itọ́

Augustin Dokla

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán, Ọrọ lori aarun Hiv

Koko HIV wa lara awọn arun to jẹ ipenija nla lagbaye ninu eto ilera lẹyin ti o ti gbẹmi eeyan bii marundinlogoji.

Ajọ to to n ri si eto ilera lagbaye(WHO) ṣalaye pe eeyan miliọnu kan to ni aarun HIV lo padanu ẹmi wọn lọdun to lọ lasan.

Iwadi fihan pe eeyan miliọnu mẹtadinlogoji lo larun HIV lagbaye ti ida aadọrin ninu ọgọrun si wa lati ilẹ Afirika- bẹẹ eeyan to din diẹ ni miliọnu meji ṣẹṣẹ lugbadi aarun ọhun ni ọdun 2017 nikan.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:

Àkọlé fídíò, WORLD AIDS DAY 2018: HIV/ AIDS kìí ṣe ìdájọ́ ikú mọ́

Ẹni to ba ni kokoro HIV nikan lo le ni aarun AIDS.

Ọpọ nnkan lawọn eeyan ti n sọ nipa aarun AIDS lati igba ti o ti kọkọ jade ni bi ogoji ọdun o din dẹ ṣẹyin.

Ṣugbọn ko si otitọ ninu ọpọlọpọ ọrọ naa.

Irọ: Mi o le ni kokoro HIV ti mo ba n bawọn to ni kokoro HIV gbe

Oni imọ ijinlẹ nipa eto ilera

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán, Ninu ẹjẹ ni aarun HIV wa

Ero yii ti ṣe okunfa ki ọpọ eeyan maa ba awọn ti wọn ni kokoro HIV ṣe papọ fun ọjọ pipẹ.

Lẹyin inalilọyẹ ati ipolongo lori aarun HIV AIDS, ida ogun ninu ida ọgọrun awọn eeyan Ilẹ Gẹẹsi si gbagbọ pe eeyan le lugbadi aarun naa nipa fifi ara kan ara tabi ninu itọ.

Ṣugbọn eeyan ko le karun HIV AIDS nipa fifi ara kan ara, tabi omi oju, oogun, itọ tabi itọ.

O ko le ko aarun HIV AIDS nipa:

  • Mimi afẹfẹ sinu
  • Didi mọ ara ẹni, fifẹnu ko ara ẹni lẹnu, tabi nipa biba ọwọ
  • Fifi abọ kan naa jẹun
  • Pipọn omi nibi kan naa
  • Lilo nkan pọ
  • Lilo ohun elo kan naa papọ
  • Fifi ọwọ kan ijoko ile iyagbẹ tabi ọwọ ilẹkun
Oloogbe ọmọbabinrin Diana pẹlu ẹni to ni aarun HIV

Oríṣun àwòrán, PA

Àkọlé àwòrán, Oloogbe ọmọbabinrin Diana pẹlu ẹni to ni aarun HIV

Kokoro HIV maa n ran nigba ti omi ara ẹnikan ba dapọ mọ ti tẹni to ba ni aarun naa, fun apẹrẹ, ẹjẹ, atọ, omi oju ara obinrin ati omi ọyan.

Irọ: Oogun ibilẹ le wo aarun HIV san

Irọ funfun balau ni. Oogun ibilẹ, iwẹ lẹyin ibalopọ tabi ibalopọ misconception ko le wo aarun HIV AIDS.

Wiwẹ pẹlu ọmọbinrin tii ko mọ ọkunrin to le wo aarun HIV AIDS san.

Kokoro HIV

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán, Itọ ko le fa aarun HIV

Irọ nla ni pe o le tara ẹfọn ni aarun HIV

Irọ ni pe o le ko aarun HIV lati ibasun ẹnu.

A condom on a banana

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán, Rọba idaabobo wulo fun idena aarun HIV

Wiwọ rọba idaabobo(condom) ko sọ pe ki eeyan maa lugbadi aarun HIV.

Alaisan to n gba ẹjẹ

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán, Aarun HIV

Irọ nla ni pe awọn to ba larun HIV maa n ku ni kekere

ọmọ tuntun

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán, Ọmọ ikoko

Alaboyun to ba ni aarun HIV, ọmọ rẹ le maa ni aarun ọhun