Njẹ ọ mọ̀ pé mímí afẹ́fẹ́ tí kò dára lè fa àìsàn?
Iwadii ti fihan wi pe awọn to n fẹsẹrin lo n koju ewu to rọmu mi mi afẹfẹ ti ko dara sinu.
Ajọ eleto ilera lagbaye, WHO fi eewu to wa ninu iru eemi bẹẹ we ewu to wa ninu ki eniyan fa siga mejila lojoojumọ.
Àwọn ìròyìn mìíràn tí ẹ lè nífẹ̀ẹ́ sí:
- Coronavirus ti di ara wa, kò le è kúrò mọ láéláé - WHO
- Àpanisáyé ni ẹ̀wà tí wọ́n n fí 'sniper' sí
- Wo ibi tí ayédèrú ìròyìn bá Áfíríkà dé láàrin ọdún kan
- Ìdí rèé tí ilẹ̀ Afirika fi gbọdọ̀ kópa nínú dídán abẹ́rẹ́ coronavirus wò
- Àwọn arẹwà obinrin Yollywood, tá ló mọ iṣẹ́ rẹ̀ jù?
- 'Àwọn akọ̀ròyìn sọ ilé ìjọba di ilé ọtí àti tẹ́tẹ́'