Ìjọba Ọ̀yọ́: Kò sí ilé kan tí wọn kò tíì bí ìbejì ní Igbó Ọrà

Àkọlé fídíò, Ìjọba Ọ̀yọ́: Kò sí ilé kan tí wọn kò tíì bí ìbejì ní Igbó Ọrà

Awọn ibeji to ba BBC Yoruba sọrọ ni ilu Igbo Ọra, lasiko ọdun ibeji to waye nibẹ ni, orisa ni ibeji, obi ti ko ba si gbe awọn jo kiri laye atijọ yoo se aisan.

Wọn wa n fapa janu pe ọlaju ti ba pataki ibeji jẹ ni awujọ wa, ti wọn si tun fi idi rẹ mulẹ pe, ti ibeji to ba n saisan, ba jẹ ẹwa, ara rẹ yoo da.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:

Kọmisọna feto iroyin, aṣa ati irinajo igbafẹ ni ipinlẹ Ọyọ, Toye Arulogun ni, ilu Igbo Ọra ni ibeji pọ si julọ ni gbogbo agbaye, ko si si ile kan ni ilu naa, ti wọn ko ti bi ibeji tabi ju bẹẹ lọ.