Buhari: Mo gbiyanju láti ma jẹ kí àwọn aṣòfin fi APC silẹ́

Aarẹ Muhammadu Buhari

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán, Buhari sni oun yoo ṣiṣẹ pẹlu gbogbo awọn ọmọ ile igbimọ aṣofin eyi o wu ti ẹgbẹ ọṣelu wọn jẹ
Ìye àkókó tí a fi kà á: Ìṣẹ́jú 1

Aarẹ orileede Naijiria,Muhammadu Buhari ni oun ti sapa ti oun lati dẹkun bi awọn aṣòfin marundilogun to jẹ ọmọ ẹgbẹ oṣelu APC tẹle ṣe paarọ aye lọ si ẹgbẹ PDP.

Igbesẹ naa ya ọpọlọpọ lẹnu ni ọjọ Isẹgun.

Aarẹ sọ lori oju opo Twitter re pe, oun mọ daju wipe, kii ṣe oun ni awọn sẹ́nétọ naa ni ija pẹlu.

O parowa si awọn ọmọ ẹgbẹ APC to ku ki wọn ma banujẹ, nitori igbesẹ awọn aṣòfin naa ko le ba nkan jẹ fun ẹgbẹ wọn bi idibo gbogbogbo 2019 ṣe n sunmọle.

Skip X post, 1
Allow X content?

This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of X post, 1

Skip X post, 2

End of X post, 2

Buhari sọ wipe oun yoo tẹsiwaju ninu iṣẹ oun pẹlu gbogbo awọn ọmọ ile igbimọ aṣòfin lalai fi ti ẹgbẹ ọṣelu wọn ṣé.

Skip X post, 3
Allow X content?

This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of X post, 3

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:

Àkọlé fídíò, APC Convention: Ààrẹ Muhammadu Buhari ti dé sí Gbọ̀gàn ìdìbò
Àkọlé fídíò, Okunrounmu: Ijọba Buhari jẹ ijiya Ọlọrun fun Naijiria