You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Ọdọ́ Tunisia yóò yan ẹni tó wù wọn sípò nídìbò abẹ́lé
Ẹẹmẹrin ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ ni wọn ti sún ètò ìdìbò abẹ́lẹ́ Tunisia síwájú
Ìdìbò 2011 ni wọn ti dìbò lórí adari Zine El-Abidine Ben Alil.
Oṣù kẹsan an ọdun to kọja ni àwọn ile igbimọ aṣofin foríji àwọn tijọba tó kógbá wọlé fẹ̀sùn jẹgúdújẹrá kàn.
Odún 2010 ni wọn dìbo ijọba ìbìlẹ̀ bayii kẹ́yìn.
Awọn ọ̀dọ̀ Tunisia ń wòye fún ọjọ́ iwájú rere lẹyìn ìdìbò òní.