Agbejọ́rò àádọ́ta wà níbẹ̀ láti ràn ọ́ lọ́wọ́ fún òmìnira rẹ

Gbogbo ẹ̀tọ́ ọmọ ènìyàn ló wà nínú ìmọ̀ ẹ̀rọ yìí.

Mọ ẹ̀tọ́ rẹ gẹ́gẹ́ bíi ọmọ Nàìjíríà gidi.

Ó jẹ́ ọ̀nà àbáyọ sí kíkọlu ẹ̀tọ́ ọmọnìyàn.

Fi ọwọ́ tẹ ìmọ̀ ẹ̀rọ 'mọ ẹ̀tọ́ rẹ' kí orí òmìnira láìṣe ojúùṣájú.

Kò yẹ kí o fi ara rẹ jìyà mọ́, ló ìmọ̀ ẹ̀rọ yìí bí o ti yẹ

Adeola Akande ló ṣe èròjà ìmọ̀ ẹ̀rọ 'mọ ẹ̀tọ́ rẹ' gẹ́gẹ́ bíi ọ̀nà àbáyọ síìṣoro kíkọlu ẹ̀tọ́ ọmọ Nàìjíríà.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: