Ẹ wo àwòrán àti ọ̀rọ̀ ìrántí àwọn akẹ́kọbìrin Chibok

Ìye àkókó tí a fi kà á: Ìṣẹ́jú 2

Ọjọ kẹrinla oṣu kẹrin, ọdun 2014, nileewe girama awọn obinrin ni ilu Chibok, nipinlẹ Borno, awọn akẹkọbinrin kan nṣe idanwo aṣekagba girama wọn lọwọ pẹlu ireti idanwo ayọ. Saadede ni awọn ẹgbẹ Boko Haram kọlu ile iwe naa ti wọn si ji awọn akẹkọbinrin naa gbe lọ

Lati igba naa, pabo ni ireti njasi lati rii pe gbogbo wọn pade sile pe. O tan kakiri agbaye lori bi ijọba to wa lode lorilẹede Naijiria lasiko naa ṣe kuna lati daabo bo awọn akẹkọ naa.

Oni lo pe ọdun kẹrin ti awọn agbebọn Boko Haram ji awọn akẹkọbinrin naa gbe, mejilelọgọfa wọn lo ṣi wa lahamọ awọn agbebọn yii.

Sibẹ́sibẹ́, bi awọn ọ̀dọmọbinrin to ku ko se tii ri itusilẹ gba lọwọ awọn ẹsinokọku Boko Haram, gbogbo igba ni ianti wọn ngba onije loju awọn obi wọn

Nigba ti isi kinni awọn akẹkọbinrin Chibok pada de, se ni inu ijọba ati gbogbo ara ilu dun bi o tilẹ jẹ wipe ọpọlọpọ aidaa lo ti sẹlẹ̀ si wọn ninu ahamọ Boko Haram

Awọn ọdọmọbinrin naa ti wọn ko sai ranti ile nibi ti iko Boko Haram gbe wọn lọ sun ẹkun ayọ

Lati ọdun ,ẹrin sẹyin ti wọn ti ko awọn ọdọmọbinrin yii sigbekun ni ọpọlọpọ ọr ti njẹyọ kaakiri agbaye. Wọ̀nyii ni lara ohun ti awọn eniyan nsọ lori ẹrọ ayelujara

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: