Ẹ wo àwòrán àti ọ̀rọ̀ ìrántí àwọn akẹ́kọbìrin Chibok

Mínísítà fún ọ̀rọ̀ àyíká pẹ̀lú àwọn akẹ́kọ̀bìnrin Chibok

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán, Òní ni àyàjọ́ ọjọ́ tí àwọn akẹ́kọ̀bìnrin Chibok sọnù
Ìye àkókó tí a fi kà á: Ìṣẹ́jú 2

Ọjọ kẹrinla oṣu kẹrin, ọdun 2014, nileewe girama awọn obinrin ni ilu Chibok, nipinlẹ Borno, awọn akẹkọbinrin kan nṣe idanwo aṣekagba girama wọn lọwọ pẹlu ireti idanwo ayọ. Saadede ni awọn ẹgbẹ Boko Haram kọlu ile iwe naa ti wọn si ji awọn akẹkọbinrin naa gbe lọ

Lati igba naa, pabo ni ireti njasi lati rii pe gbogbo wọn pade sile pe. O tan kakiri agbaye lori bi ijọba to wa lode lorilẹede Naijiria lasiko naa ṣe kuna lati daabo bo awọn akẹkọ naa.

Awọn akekọbinrin Chibok

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán, Abọde awọn akẹ́kọbinrin Chibok

Oni lo pe ọdun kẹrin ti awọn agbebọn Boko Haram ji awọn akẹkọbinrin naa gbe, mejilelọgọfa wọn lo ṣi wa lahamọ awọn agbebọn yii.

Aarẹ Muhammadu Buhari pẹlu awọn akekọbinrin Chibok

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán, Ijọba apapọ orileede se ajoyo awọn akekọbinrin Chibok to kọkọ pada de

Sibẹ́sibẹ́, bi awọn ọ̀dọmọbinrin to ku ko se tii ri itusilẹ gba lọwọ awọn ẹsinokọku Boko Haram, gbogbo igba ni ianti wọn ngba onije loju awọn obi wọn

Obi akekobinrin Chibok

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán, Obi awon akekobinrin Chibok ko tii dake riranti awon omo won

Nigba ti isi kinni awọn akẹkọbinrin Chibok pada de, se ni inu ijọba ati gbogbo ara ilu dun bi o tilẹ jẹ wipe ọpọlọpọ aidaa lo ti sẹlẹ̀ si wọn ninu ahamọ Boko Haram

Igbakeji Aarẹ, Yẹmi Ọsinbajo pẹ̀lu akẹ́kọbinrin Chibok

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán, Igbakeji Aarẹ, Yẹmi Ọsinbajo nigba to nki awọn akẹkọbinrin Chibok to ti de sile ku abọ

Awọn ọdọmọbinrin naa ti wọn ko sai ranti ile nibi ti iko Boko Haram gbe wọn lọ sun ẹkun ayọ

Iyawo igbakeji Aarẹ, Dolapọ Ọsinbajo yọ̀ pẹlu awọn akẹkọbinrin Chibok

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán, Iyawo igbakeji Aarẹ, Dolapọ Ọsinbajo yọ̀ pẹlu awọn ọmọ naa

Lati ọdun ,ẹrin sẹyin ti wọn ti ko awọn ọdọmọbinrin yii sigbekun ni ọpọlọpọ ọr ti njẹyọ kaakiri agbaye. Wọ̀nyii ni lara ohun ti awọn eniyan nsọ lori ẹrọ ayelujara

Skip X post, 1
Allow X content?

This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of X post, 1

Skip X post, 2

End of X post, 2

Skip X post, 3

End of X post, 3

Skip X post, 4

End of X post, 4

Awọn ara ilu Chibok

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán, Awọn obi ati ara ilu Chibok si nreti awọn ọmọ to ku

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:

Àkọlé fídíò, ‘Ara fu mí nígbàtí bàbá gbé Bíbélì ìdílé fúnmi’