‘ Awọn ọmọ Yobe’: Ibeere mẹrin to n ja ranyinranyin

Oríṣun àwòrán, Yobe state governmentt
Titi di bi a se n sọrọ yii,ko tii si aseyọri kan pato lori awari awọn ọmọ ileewe Girama ẹkọsẹ ọwọ awọn obinrin nilu Dapchi ni ipinlẹ Yobe lẹyin isẹlẹ to sẹ ni ọjọ aje nibiti awọn akẹkọ ileewe naa kan ti di awati.
Amọsa ni bayii awọn ibeere kan ti n ja ranyinranyin kaakiri.
Eni- Se wọn yoo di ohun elo ado oloro fun ikọ Boko haram ni?

Oríṣun àwòrán, Getty Images
Eji- Se awọn naa yoo di ohun elo pasipaarọ laarin ijọba ati Boko Haram ni?

Oríṣun àwòrán, Getty Images
Ẹta- Se awọn naa yoo di aya tipatipa fun awọn agbesunmọmi Boko Haram ni?

Oríṣun àwòrán, Getty Images
Ẹrin-Se awọn ọmọbinrin ti wọn ji gbe yii yoo lee pada si ileewe mọ?

Oríṣun àwòrán, Getty Images








