Africa's week in pictures: Àwọn àwòrán tó làmílaaka nílẹ̀ Afrika ní ọ̀ṣẹ́ yìí rèé

Àkójọpọ̀ àwọn àwòrán tó làmílaaka nílẹ̀ Afrika ní ọ̀ṣẹ́ yìí rèé.

Arakunrin lati ẹya Maasai ni orilẹede Kenya lo n fọ fere lati ṣe ayẹyẹ ayajọ Ọjọ Ibilẹ lagbaye.

Oríṣun àwòrán, Gerald Anderson/Anadolu Agency

Àkọlé àwòrán, Arakunrin lati ẹya Maasai ni orilẹede Kenya lo n fọ fere lati ṣe ayẹyẹ ayajọ Ọjọ Ibilẹ lagbaye.
Arakunrin ẹya Maasai miran ree to wọ aṣọ ibilẹ rẹ fun ayẹyẹ ọjọ ibilẹ ni agbaye kan naa.

Oríṣun àwòrán, Gerald Anderson/Anadolu Agency

Àkọlé àwòrán, Arakunrin ẹya Maasai miran ree to wọ aṣọ ibilẹ rẹ fun ayẹyẹ ọjọ ibilẹ ni agbaye kan naa.
Aluwẹ, Jarden Dylan Eaton lati ilẹ South Africa ree nibi to ti n kopa ninu idije Youth Commonwealth Games to waye ni Trinidad and Tob

Oríṣun àwòrán, Matt McNulty/Getty Images

Àkọlé àwòrán, Aluwẹ, Jarden Dylan Eaton lati ilẹ South Africa ree nibi to ti n kopa ninu idije Youth Commonwealth Games to waye ni Trinidad and Tobago.
Ni orilẹede Morocco ti awọn eniyan ti n ṣe ọdun Moussem to ma n waye ni ọdọọdun

Oríṣun àwòrán, Fadel Senna/Getty

Àkọlé àwòrán, Ni orilẹede Morocco ti awọn eniyan ti n ṣe ọdun Moussem to ma n waye ni ọdọọdun
Ẹlẹsin ree lati Morocco to n wa ẹsin rẹ ninu agbami nla ti Atlantic Ocean lati ṣe ayẹyẹ ọdun wọn ni ọdọọdun.

Oríṣun àwòrán, Fadel Senna/Getty

Àkọlé àwòrán, Ẹlẹsin ree lati Morocco to n wa ẹsin rẹ ninu agbami nla ti Atlantic Ocean lati ṣe ayẹyẹ ọdun wọn ni ọdọọdun.
Dillon Geary lati ilẹ South Africa ree nibi to ti n kopa ninu idije awọn awakeke ''Cycling World Championship'' to waye ni Glasgow.

Oríṣun àwòrán, Dario Belingheri/Getty

Àkọlé àwòrán, Dillon Geary lati ilẹ South Africa ree nibi to ti n kopa ninu idije awọn awakeke ''Cycling World Championship'' to waye ni Glasgow.
Awọn eniyan ree nibi ti wọn ti n gba atẹgun ti wọn si n luwẹ ninu omi lasiko oju ọjọ gbigbona ni orilẹede Egypt.

Oríṣun àwòrán, Mohamed Abd El Ghany/ Reuters

Àkọlé àwòrán, Awọn eniyan ree nibi ti wọn ti n gba atẹgun ti wọn si n luwẹ ninu omi lasiko oju ọjọ gbigbona ni orilẹede Egypt.
Ọmọ Naijiria, Destiny Nkemakonam Agbo fi idunnu han lẹyin to gba ade ni ere idaraya ''Discus'' to waye ni idije 2023 Youth Commonwealth Games.

Oríṣun àwòrán, Jamie Squire/Getty

Àkọlé àwòrán, Ọmọ Naijiria, Destiny Nkemakonam Agbo fi idunnu han lẹyin to gba ade ni ere idaraya ''Discus'' to waye ni idije 2023 Youth Commonwealth Games.
Awọn alatilẹyin ikọ ọmọogun Niger to gba ijọba nibẹ ṣe iwọde lati fi atilẹyin wọn han fun ijọba ologun naa.

Oríṣun àwòrán, -

Àkọlé àwòrán, Awọn alatilẹyin ikọ ọmọogun Niger to gba ijọba nibẹ ṣe iwọde lati fi atilẹyin wọn han fun ijọba ologun naa.
Ẹgbẹ agbabọọlu Rugby ti ilẹ South-Africa fi idunnu wọn han lẹyin ti wọn fi akọ yọ nibi idije to waye ni Argentina lẹyin ti wọn na ikọ Argentina ti wọ

Oríṣun àwòrán, Marcelo Endelli/Getty

Àkọlé àwòrán, Ẹgbẹ agbabọọlu Rugby ti ilẹ South-Africa fi idunnu wọn han lẹyin ti wọn fi akọ yọ nibi idije to waye ni Argentina lẹyin ti wọn na ikọ Argentina ti wọn si gba ade.
Awọn alatilẹyin ẹgbẹ oselu Zanu-PF to wa ni ipo adari ijọba lọwọ ni Zimbabwe, se iwọde lati ṣe atilẹyin fun ẹgbẹ naa saaju idibo ti yoo waye ni Ọjọ Kẹtalelogun, Osu Kẹjọ, ọdun 2023.

Oríṣun àwòrán, EPA-EFE/REX/Shutterstock

Àkọlé àwòrán, Awọn alatilẹyin ẹgbẹ oselu Zanu-PF to wa ni ipo adari ijọba lọwọ ni Zimbabwe, se iwọde lati ṣe atilẹyin fun ẹgbẹ naa saaju idibo ti yoo waye ni Ọjọ Kẹtalelogun, Osu Kẹjọ, ọdun 2023.
Aworan Kiniun ree nibi to dọbalẹ si ni agbegbe Maasai Mara ni orilẹede Kenya lati ṣe ayajọ ọjọ awọn Kinium lagbaye ni Ọjọ Kẹwaa, Osu Kẹjọ, ọdun 2023.

Oríṣun àwòrán, Gerald Anderson/Anadolu Agency

Àkọlé àwòrán, Aworan Kiniun ree nibi to dọbalẹ si ni agbegbe Maasai Mara ni orilẹede Kenya lati ṣe ayajọ ọjọ awọn Kinium lagbaye ni Ọjọ Kẹwaa, Osu Kẹjọ, ọdun 2023.

Images subject to copyright