Yunus Abiodun Akintunde tó ń du ipò sẹ́nẹ́tọ̀ ààrin-gùngùn Oyo lábẹ́ àsìá APC ní sọ ohun tó ní lọ́kàn láti ṣe tó bá wọlé
Omowe Yinusa Abiodun Akintunde to n dije dupo aṣojuṣofin ni aarin gbungbun ipinle Oyo sọrọ ilẹ kun.
O menuba awọn iṣe to ti se sẹyin lati aye ẹgbẹ Imọlẹ UPN titi lọ ba ẹgbẹ AD.
Yinusa Abiodun tun sọ nipa iṣẹ to ṣe lasiko ti awọn gomina bii oloogbe Lam Adesina ati oloogbe Abiola Ajimobi yan oun sipo nigba naa
- 'Òǹtàjà aṣọ ni mí tẹ́lẹ̀, ọ̀dá owó ló sọ mi di alábárù'
- Mo ti di 'Millionaire' kí n tó pé 18 rárá, ìdí iṣẹ́ arìnrìnoge ni mo ti di òṣèré- Omotola Jalade Ekeinde
- Bí 2023 ṣe wọlé dé wẹ́rẹ́, Alapinni Oosa wúre ọdún fún ọmọ Yorùbá
- Ẹ máa ṣe àmín bí Adewale Alebiosu, àgbà òṣèré tíátà, ṣe ń gbàdúrà ọdún túntún fún yín
- Àánú táwọn èèyàn yóò fi máa sọ wí pé ọ̀nà wo lo gbà ni yóò wọlé fún ọ ní ọdún 2023
- Ẹni bá láyà: Ṣé ìwọ mọ àmì Yorùbá dáadàa?
Oludije labe APC yii, Abiodun Akintunde só pe Tinubu Bola lo to lati figagbaga pẹlu enikeni lati dije dupo aare ni Naijiria lasiko yii pẹlu awon nkan to ni lọkan lati ṣe fun awọn ara ilu ni kete to ba wọle sipo to n dije fun