You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Aláànú àti Olùfọkànsìn ní tókótaya Kehinde àti Bukola Fatinoye- Alufaa S K Oyewale
Gbogbo eeyan ni à\won tọkọtaya yii n ran lọwọ lai ni igberaga- Alufaa ijọ wọn.Àwọn oníṣẹ́ ibi tó pa tọkọtaya náà de àwa tí a kọ́kọ́ dé síbẹ̀ mọ́lẹ̀- Ó ṣojú mi
BBC Yoruba ti wa Alufaa agba ijọ ti tokotaya Fayinoye n lo ni Iporo Ake ni ilu Abeokuta, ni ipinle Ogun to wa ni iwo oorun guusu Naijiria kan.Wọn ti rí òku Ooreoluwa, ọmọ tọkọtaya tí wọ́n dáná sún ni Abeokuta lọ́jọ́ ọdún, wo ohun tí ọlọ́pàá Ogun tún sọ..-
Al;ufaa agba S. Kolawole Oyewale to n dari ijọ Christ Anglican Church ni Iporo Ake ni Abeokuta ṣalaye iru eeya ti tọkọtaya Kehinde ati Olubukola Fatinoye jẹ fun BBC pe Aláànú àti Olùfọkànsìn ní tókótaya Kehinde àti Bukola Fatinoye.
Bakan naa lo sọ nipa asiko igbẹyin awọn oloogbe naa ninu ijọ lasiko isin ọdun tuntun naa.
O tun fi igabgbọ rẹ han leyin iku pe wọn ti lọ sinmi laya Olugbala wọn bayii.
- Ó kéré tán ìkọ̀ ọmọogun Russia 400 ló kú ní ìkọ̀lù àdó olóró – Ukraine
- Ọrọ̀ ajé ọ̀pọ̀ orílè-èdè àgbáyé ni yóò dojúkọlẹ̀ ní 2023- IMF ṣe ìkìlọ̀
- Babaláwo kú sórí ìyàwó 'pásítọ̀' nílé ìturá ní Ikere-Ekiti
- A ti parí ìgbésẹ̀ láti gbé gbogbo àwọn ọlọ́pàá àgọ́ Ajah- Iléeṣẹ́ ọlọ́pàá Eko
- Ghana, Morocco,fi òfin de ìrìnàjò láti China lẹ́yìn tí Covid-19 tún búyọ níbẹ̀
Kini olopaa sọ bayii?
Oga ọlọpaa Abimbola Oyeyemi ti o je alukoro ọlọpaa ipinlẹ Ogun naa ti ba BBC Yoruba sọrọ lori iṣẹlẹ buruku yi.
O ni ohun ibanujẹ ni.
Oyeyemi ṣalaye bi wọn se ri oku ọmọ awọn tokotaya yii ati bi wọn se ri ẹnikan to n ba won gbe.
Ọwọ́ ọlọ́pàá ti tẹ afurasí kan lórí ìṣekúpa tọkọtaya tí wọ́n dáná sun ni Abeokuta- Iléeṣẹ́ ọlọ́pàáá
Alábàgbé tọkọtaya ti wọ́n pa ní Ogun wà láàyè, ó wà ní ìpamọ́, ìwádìí n lọ lọ́wa báyìí- Oyeyemi Sgá ọlọ́pàá Ogun.
- Ẹ máa ṣe àmín bí Adewale Alebiosu, àgbà òṣèré tíátà, ṣe ń gbàdúrà ọdún túntún fún yín
- Àánú táwọn èèyàn yóò fi máa sọ wí pé ọ̀nà wo lo gbà ni yóò wọlé fún ọ ní ọdún 2023
- Ẹni bá láyà: Ṣé ìwọ mọ àmì Yorùbá dáadàa?
- Bí 2023 ṣe wọlé dé wẹ́rẹ́, Alapinni Oosa wúre ọdún fún ọmọ Yorùbá
- Èrè tó pọ̀ ni gbogbo Oníṣòwò máa jẹ ní 2023- Imam Sabit Olagoke
- 'Oníṣègùn, alágbo, aláàfáà, aládurà, gbogbo èèyàn ló ń wá ra ìkòkò àmọ̀ wa'