You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Alapinni Oosa ṣàdúrà fún gbogbo ọmọ kúoótù, oò jíire bí?
Òjòjò kò ni ṣowó kó má ná ọjà, ko ko ko ni ara ọta gbogbo yin a maa le.
Eyi ni ibẹrẹ adura opin ọdun ati ti ọdun tuntun ti Alapinni Ooṣa n se fun gbogbo ọmọ Kaarọ o jiire.
Bí Ọdún 2022 se ko igba wọle, tí ọdun tuntun, 2023 wọle de wẹrẹ, ni BBC Yorùbá gbadura fún gbogbo ẹyin ololufẹ wa pe:
Yọ̀bọ̀ ti ìgbín n yọ̀ ni ki gbogbo yin máa yọ̀ jábọ́ kuro lọwọ ewu gbogbo tó wà ninu ọdun tuntun yii.
Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:
- Kí lo fẹ́ mọ̀ nípa ‘Ajala Travels’?
- Ṣẹ gbọ́ nípa Alájọ Ṣómólú, tó ta mọ́tò ra kẹ̀kẹ́?
- Ẹfunroye Tinubu - Ògbóǹtagí oníṣòwò, olówò ẹrú àti afọbajẹ
- Samuel Ajayi Crowther, òjíṣẹ́ Ọlọ́run tó gbé èdè Yoruba lárugẹ
- Mọrèmi Àjàṣorò, akọni obìnrin tó gba Ilé Ifẹ̀ sílẹ̀ lóko ẹrú
- Ọ̀rọ̀ǹpọ̀tọ̀niyùn, Aláàfin obìnrin àkọ́kọ́ rèé, tó ní nǹkan ọkùnrin
- Baṣọ̀run Gáà, tó yan ọba mẹ́rin, pa ọba mẹ́rin àmọ́ ọba karùn-ún ló pa á
- Ohun tóo gbúdọ ṣe lọ́dún yìí bí o bá fẹ́ kí Ọlọ́run bá ọ rìn- Abiara
Ganiu Nafiu ti gbogbo ololufẹ Yollywood mọ si Alapinni Ooṣa ti ṣe iwure ọdun tuntun pe ohun gbogbo ti koowa ba ti n lù si daadaa ni o maa dún tó maa dùn láti jó sí lawujọ.
Ọdun tuntun ti wọle de lagbaye, ọdun naa jẹ ọdun ireti ọpọlọpọ paapaa fun isinmi ati alaafia lori ohun gbogbo to n ṣẹlẹ kaakiri agbaye lasiko yii
Ọdun tuntun yii a dun fun gbogbo wa, eso alaafia a kari lọọdẹ koowa wa.