You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Ẹ wá gbọ bí òwe Yoruba ṣe dùn lẹnu ọmọ Igbo
Imado iba ṣe bi ẹlẹdẹ a balu jẹ, ẹru iba j’ọba, eeyan iba ku ọkan.
Pupọ ninu awọn ọmọ ilẹ Yoruba lo maa n gbọ owe oke yii ṣugbọn ti wọn kọ mọ itumọ rẹ.
Ṣaṣa ninu awọn ọmọ Yoruba, paapaa awọn ọmọ aye ode oni ni ko tilẹ mọ iru ẹranko to n jẹ imado, anbelete itumọ owe naa.
Ṣugbọn ki ni imado? Iru ẹranko wo ni Yoruba n pe ni imado?
Ki ni itumọ owe yii ati pe bawo ni owe naa ṣe jọ mọ ohun to n ṣẹlẹ laye ode oni?
Ẹ wo fidio yii fun ẹkunrẹrẹ bii ọmọ Igbo, Jude Chukwuka ṣe ṣe atupalẹ owe naa.