You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Ọkọ̀ tí kò bá ti kun ọdà àwọ ọkọ̀ akérò yóò bẹ̀rẹ̀ sí ní wọ gbaga òfin l'Eko - LASTMA
Ko si aye fun awọn awakọ ero ti ko kun ọkọ wọn ni ọda awọn pupa ati awọ yẹlo pẹlu ile dudu meji tẹẹrẹ lara rẹ gẹgẹ bi ijọba ipinlẹ Eko ṣe laa silẹ mọ loju popo ni ipinlẹ Eko.
Ọga agba ajọ igbokegbodo ọkọ nipinlẹ Eko LASTMA, Ọgbeni Bolaji Ọrẹag a sọ pe ìjọba ti ṣetan lati maa gbẹsẹ le irufẹ awọn ọkọ ti ko kun ọda wọnyii loju popo nipinlẹ Eko.
Orẹagba fi kun un pe igbesẹ yii ko ni eredi meji ju ọna lati rii daju pe awọn ọkọ akero gbogbo nipinlẹ Eko tẹlẹ ilana ati aṣẹ ti de lilọ bibọ ọkọ.
Ọga agba ajọ LASTMA naa tun ṣalaye pe awọn ẹṣọ agbofinro ijọba yoo bẹrẹ si ní ṣíṣe lori igbesẹ yii lati ọjọ Aje ọjọ keje oṣu kọkanla ọdun 2022 kaakiri ipinlẹ Eko.
- 'Inú ewu ńlá ni gbogbo àgbáyé wà báyìí lórí ọ̀rọ̀ àyípadà ojú ọjọ́'
- Adedoyin àti afurasí yókù ní àwọn kó jẹ̀bi ẹ̀sùn ípànìyàn tí iléẹjọ́ fí kàn wọn
- World Cup 22- Àwọn ọ̀nà àrà láti mú pápá ìṣeré tutù ní ìlú aṣálẹ̀
- Bayo Adelabu ké sí gómìnà Seyi Makinde kọ̀wé fipò sílẹ̀ nítorí ìkùnà ìjọba rẹ̀
- Ọlọ́pàá mú ọkùnrin tó d-áná sun ọmọ ìyàwó rẹ̀ márùn-ún ní Ondo
- D-ino Melaye àti Peter Obi gbéná wojú ara wọn níbí ìtàkurọ̀sọ àwọn olùdíjé sípò ààrẹ
Oga LASTMA ni ikilọ naa waye lati rii daju pe awọn ọlọkọ ero ni ipinlẹ Eko tẹ le ilana ofin ti wa nilẹ lori atunṣe irinna ọkọ Lagos State Transport Sector Reform Law, 2018 lati lee da alaafia pada si oju popo ati lati daabo bo ẹmi ati dukia araalu.
O salaye pe gbogbo awọn ọkọ Danfo ati korope Lo gbọdọ kun ọda awọ yẹlo pẹlu ila dudu tẹẹrẹ meji, nigba ti awon ọkọ akero nlanla gbọdọ kun ọda awọ pupa ti ijọba fọwọsi.
O ni aṣẹ ti jade si gbogbo awọn ẹṣọ agbofinro LASTMA lati bẹrẹ si ni fi panpẹ ofin gbe gbogbo ọkọ to ba tapa si ofin yii, bẹẹni ọkọ tọwọ ba tẹ yoo wa ni gbaga ajọ naa titi di igba ti ọlọkọ naa ba ṣe ohun to tọ.
- -Ọkọ mi kò ráyè wọ ojú ara mi láti já ìbálé lẹ́yìn oṣù kan ta ṣe ìgbéyàwó-
- Ojútì, ìrẹ́nijẹ àti ìyà àìkàwé nídìí iṣẹ́ tíátà ti ọ̀pọ̀ òṣèré padà sí fásitì
- Báwo ni o ṣe gbọ́ èdè Yorùbá sí?
- Àwa kọ́ la rán àwọn tó ṣèkọlù sí ikọ̀ ọmọogun Naijiria, a ò mọ̀ wọ́n rí – Ilana Ọmọ Oodua
- 100 ọmọ ló ń kú ní Nàìjíríà láàrín wákàtí kọ̀ọ̀kan lójúmọ́- UNICEF
- A kò lé sàn owó Iṣẹ́ tí àwọn olùkọ́ Fásitì kò ṣe fún wọn- Ìjọba Àpapọ̀