Robert Omoigbe sọ irinajọ rẹ lo si Morocco ati bi o ṣe bẹrẹ iṣẹ tita ounjẹ ilẹ Naijiria.

Àkọlé fídíò, Robert Omoigbe sọ irinajọ rẹ lo si Morocco ati bi o ṣe bẹrẹ iṣẹ tita ounjẹ ilẹ Naijiria.

Arakunrin Robert Omoigbe ni oun bẹrẹ tita ounjẹ ilẹ Naijiria nitori ti awọn ba jẹ ounjẹ ilẹ Morocco, o ma n run wọn ni inu.

Omoigbe sọ iriri rẹ lasiko to n ba BBC Yoruba sọrọ ni Morocco lori bi oun ṣe bẹrẹ tita ounjẹ nitori aisi iṣẹ ni Morocco.

''Igba ti ko si iṣẹ ni Morocco ni mo woye lati bẹrẹ iṣẹ tita ounjẹ ilẹ Niajiria ni Morocco''

''Mo jere lọpọ nibẹ nitori ọwọ ilẹ Morocco ni agbara ju owo ilẹ Naijiria lọ''

Wo ẹkunrẹrẹ alaye lori bi o ṣe bẹrẹ iṣẹ naa ati ohun to ti gbeṣe.