BBC Ekiti Debate: Mo setán láti ra ògo ìpínlẹ̀ Ekiti padà- Erelu tó n dije lábẹ́ ADP
Oludije egbe Oselu ADP salaye awon nkan to le sun ipinle Ekiti siwaju to ba wole bii gomina.
Erelu Elebute Halle to n dije dupo gomina ipinle Ekiti labe asia egbe oselu ADP sọ̀rọ̀ ilẹ̀ kun lasiko ti BBC seto wa wi ténu é fawon oludije sipo gomina nibẹ̀.
BBC té pépé eto ipade itagbangba naa ki onikaluku wa sọ̀ ohun to ni lọ́kan fawon oludibo ni ipinle Ekiti.
Nibe ni Erelu yii ti sọ̀rs lori ipa obinrin lasiko yii ninu oselu ati awọ̀n ohun to ni fun eto ẹ̀kọ́, eto ilera, eto aabo ati awon ọ̀dọ́ ipinlẹ̀ Ekiti to ba jawe olubori ninu idibo to m bo losu yii.
- 'Àwa ni "Zama Zama"! À ń gbé labẹ́ ilẹ̀ láti wa góòlù jáde àmọ́ bí ikú ṣe ma ń mú wa lọ rèé'
- ''Àwọn adìyẹ tí mò ń sìn ni mo ń fún ní Indian Hemp mu ''
- APC àti PDP ní láti túká, ìdí rẹ̀ rèé
- Ará ìlú kò lè máa dá owó fún ìjọba, ohun tí mo fẹ́ ṣé rèé tí àwa ará Ekiti yóò ní owó tiwa - Olùdíjé ADC
- ''Àwọn adìyẹ tí mò ń sìn ni mo ń fún ní Indian Hemp mu ''