Ukraine and Russsia crisis: Aáwọ̀ tó wà láàrin Russia àti Ukraine ti mú àlékún bá iye owó epo rọ̀bì lágbàyé

Àkọlé fídíò, Aáwọ̀ tó ń wáyé láàárín Russia àti Ukraine ti mú àlékún bá iye owó epo rọ̀bì lágbàyé

Ikolu Russi a si Ukraine ti di amojuto gbogbo agbaye bayii

Saaju ni Aare mejeeji ti jo kede lati jo na an tan bi owo ni.Wo ìdí pàtàkì mẹ́ta tí Russia se kọlu Ukraine

Leyin naa ni ọ̀ps awon olugbe Ukraine ti n sa asala fun emi won Kílódé tí NATO kò ṣe fẹ́ gbè lẹ́yìn Ukraine?

Kí ni ipa tí ìkọlù Russia sí Ukraine le ní lórí ilẹ̀ Adúláwọ̀

BBC Yoruba se agbeyewo ohun to n sele laarin Ukraine ati Russia ati bi o se le ni ipa lori iwo ti o n gbe nile Afrika lori eto Laa Han Mi.

Laa Han Mi
Àkọlé àwòrán, Laa Han Mi lórí Russia àti Ukraine

Kini Eto Laa Han Mi lori BBC Yoruba jẹ́?

Eto Laa Han Mi ni a fi n satupale ohun ti ko ye awon ololufe BBC to lasiko to ba n sele.

Laa Han Mi
Àkọlé àwòrán, Laa Han Mi

Ukraine ló ń pèsè oúnjẹ wooro jù lágbàyé, àwọn orílẹ̀ èdè bí i Tunisia, Egypt, Morocco àti Libya yóò mọ ìkọlù láàárín àwọn orílẹ̀ èdè méjéèjì yìí lára púpọ̀.

Bẹẹ ba si gbagbe, aarẹ Putin ti se ikilọ saaju lọsẹ to kọja pe "ẹnikẹni to ba n gbero lati da si aawọ Russi ati Ukraine lati ita - ni oju wọn yoo ri ohun ti oju ẹnikẹni ko ri ri ninu itan."

Laa Han Mi