Adepoju Abdulsalamm ẹni ọdun 18 tó n fi kẹ̀kẹ́ dára fi kiri ẹja tó fi n tà wàràwàrà

Àkọlé fídíò, Adepoju Abdulsalamm ẹni ọdun 18 tó n fi kẹ̀kẹ́ dára fi kiri ẹja tó fi n tà wàràwàrà

Ki n to wọ ileẹkọ giga ni mo ti n kiri ẹja fi ran iya mi lọwọ titi di isinyi- Abdusalam

Abdulsalam Adepọju jẹ ẹni ọdun mejidinlogun to n ba iya rẹ fi kẹkẹ kiri ẹja.

Orisirisi ọna lo maa n fi kẹkẹ gigun rẹ dara ni eyi ti o maa n jẹ ki o fi ta daadaa

Eleja
ẹlẹja

Koda, awọn onibara Adepoju Abdulsalam sapejuwe rẹ gẹgẹ bi ẹni to ṣee fi ọkan tan nigba ti ẹ ba ti pe e pe ko gbe ẹja wa.

Eleja

Iya rẹ to jẹ Opó ṣalaye ohun ti oju rẹ ti ri lati ọdun kẹsan an ti ọkọ rẹ ti ku.

Bakan naa lo mẹnuba iranlọwọ ti Abdulsalam n ṣe fun oun lati igab to ti n ba a kiri ẹja.

Eleja

Abdulsalam Adepoju ni o wu oun lati kawe sii lọjọ iwaju.