Yinka Adesanya Oke: Àrà tuntun tí aṣọ òkè Yorùbá ń gbé jáde ti di àwò-dami-ẹnu lásìkò yìí
Aṣọ òkè gbàràdá, ó di ọmọ tuntun ti gbogbo ayé ń pé wò lọ́jà.
Abilekọ Yinka Adesanya Oke tó jẹ akọṣẹmọṣẹ lórí ṣiṣẹ ọ̀ṣọ́ si àṣọ oke ba BBC Yorùbá sọ̀rọ̀ lori ọmọ ti ayé bí ti ayé ń pọ̀n bayii nibi ẹ̀ṣọ́ ṣiṣe si ara aṣọ oke Yoruba.
Aṣọ oke Yoruba gbayii ni ode ọmọluwabi gbogbo bii igbeyawo, ikomọjade, ifinijoye, iṣile àti bẹẹ bẹẹ lọ.
Laye atijọ, ìró àti bùbá ni fun obinrin ṣugbon bayii, igba ti yipada, Yinka Oke sọrọ lori àwọn àrà oniruuru ti àwọn eniyan n fi aṣọ oke da lasiko yii.
Bi o ṣe jẹ́ akẹkọọ oye ọmọwe (Ph.D) ni fasiti Eko naa lo tun jẹ òntajà aṣọ òkè tó ń ṣe é lọ̀ṣọ̀ọ́ ní onírúurú ọ̀nà tí oníbarà bá fẹ́ lati fi gbe ogidi àṣà Yoruba ga.
Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ sí:
- Obinrin Yollywood wo lọjà rẹ̀ tà jù lọ́wọ́ yìí?
- Nàìjíríà kàn takú ni, ẹ ò páàsì, ẹ ò féèlì, ẹ ò kúrò ní kíláàsì kan náà- Àwọn ọ̀dọ́
- Àwọn ọ̀nà tí obìnrin fi le gbádùn ìbálòpọ̀
- Àánú ni mo ṣe láti fẹ́ Duro Ladiipo ṣùgbọ́n kò fi mi sílẹ̀ láti 1962, ọ̀rọ̀ ìfẹ́ wa dùn púpọ̀- Abiodun Duro Ladiipo
- Ṣé ìwọ mọ ìtàn Ibadan àti ìgbín mẹ́rin? ipá wo ni Abuké àti Àfín kó nínú ìtàn Ibadan?
- 'Dokita ilé ìwòsàn ló gba ẹsẹ̀ lọ́wọ́ mi'