Osun ritual killer: Ọwọ́ ọlọ́pàá ti tẹ Kabiru tó pa ọ̀rẹ́bìnrin rẹ̀ tó sì ṣá a wẹ́lẹwẹ̀lẹ bí màlúù ní Apomu

Oríṣun àwòrán, Newsdayng.com
Ọwọ awọn ọlọpaa ni ipinlẹ Ọṣun ti tẹ arakunrin ẹni ogoji ọdun kan ti wọn fura si pe o jẹ apaniṣetutu ọla.
Ọwọ tẹ arakunrin naa ti orukọ rẹ n jẹ Kabiru Oyeduntan lẹyin to pa ọrẹbinrin rẹ to si duu wẹlẹwẹlẹ.
- A kò ní ṣe ètò ìsìnkú TB Joshua ní bòńkẹ́lẹ́ - Evelyn Joshua
- Kìí ṣe Gómìnà Seyi Makinde ló ṣètò ìwọ́de June 12 ní Ibadan kò sì bá wọn kópa - Taiwo Adisa
- Bobrisky fi òkò ọ̀rọ̀ ránṣẹ́ sáwọn tó ń ro ikú rò ó torí iṣẹ́ abẹ ìdí tó ṣe
- Kudirat Abiola: Akọni obìnrin tó jẹ́ ọ̀wọ̀n ìrántí fún àyájọ́ ìjọba alágbádá
- ₦324bn la pín fún 136,000 oníṣòwò ké kè ké lásìkò ìgbélé Covid-19 - Buhari
Agbegbe quarry ni ilu Apomu ni iṣẹlẹ naa ti waye.
Ni ọjọbọ lawọn eeyan kan ta ọlọpaa lolobo ni nnkan bii agogo mẹsan alẹ tawsn ọlọpaa fi ka arakunrin naa mọ ibi ti o ti ṣa ọrẹbinrin rẹ naa ti sjọ ori rẹ ko ju ogun ọdun lọ wẹlẹwẹlẹ.
Bakan naa lawọn ọlọpaa ṣe akiyesi pe awọn ẹya ara arabinrin naa kan ko si nibẹ mọ, lẹyin eyi ni wọn wa tẹle arakunrin naa lọ si ile rẹ nibi ti wọn ti ri ori, ọrun ọwọ atawọn ẹya ara miran.
Amọṣa wọn ko ri awọn kan nibẹ mọ









