Fuel Hike: Wo iye tí epo bẹtiróò jẹ́ láwọn ìpínlẹ̀ Nàìjíríà

Ile Epo, ati iye ti jala epo je

Gbogbo ọmọ Naijiria lo n ke rara lana ode yii lẹyin ti ẹka ijọba ti n ri si ọrọ iye ti epo rọọbi yoo jẹ tita labẹle polongo loju twitter rẹ pe epo bẹtiro ti di igba kan naira ati naira mejila.

Lẹyin ọpọlọpọ ariwọ awọn ọmọ Naijiria ni akọle naa dede poora loju opo ọhun.

Bakan naa ni minisita to n ri si ọrọ epo nilẹ wa tun fi atẹjade kan sita pe, ko si nkan to jọ pe ijọba fowo kun owo owo epo ati pe ibi yoo wu ki awọn ọmọ Naijiria ba ti gbọ, iru ikede bẹẹ ko lẹsẹ nilẹ.

Ẹwẹ ipe ti ile isẹ iroyin BBC Yoruba fi sita loni fun ara ilu lati maa sọ iye ti wọn n ta epo lagbegbe wọn, eyi lo fi ye wa pe awọn miran tilẹ n ra epo ni owo to to ogun nairia din ni ọọdunrun.

Diẹ lara awọn ti ale fi han yoo re:

Fuel Hike: Iye tí epo bẹtiróò jẹ́ láwọn ìpínlẹ̀ Nàìjíríà

Razaq Salaujdeen ni adugbo rẹ ni ipinlẹ Ogun salaye pe igba naira ati naira mẹẹdogun ni awọn ra epo naa lonii.

Fuel Hike: Iye tí epo bẹtiróò jẹ́ láwọn ìpínlẹ̀ Nàìjíríà

Oríṣun àwòrán, Razaq Salaudeen

Fuel Hike: Iye tí epo bẹtiróò jẹ́ láwọn ìpínlẹ̀ Nàìjíríà
Fuel Hike: Iye tí epo bẹtiróò jẹ́ láwọn ìpínlẹ̀ Nàìjíríà
Fuel Hike: Iye tí epo bẹtiróò jẹ́ láwọn ìpínlẹ̀ Nàìjíríà
Ọ̀rọ̀ iye jálá epo ṣe ọ̀tọ̀ọ̀tọ jákàjádò orílẹ̀ èdè Nàìjíríà.

Prince Adeyemo Azeez Ayomi ni tirẹ ni: "Mora ni 162 ni ileepo Oando lagbegbe iyaganku ni Ibadan"